Kangaroo n çranko afikùn gbömô rê põn
keep v fi pamö, töjú kennel n ilé ajá ketchup n onjç oní tùmátì dídùn kettle n ìkòkò bíbô omi, ohun èlò omi key n kökörö, ômô ìÿíkà, ômô àgàdàgodo, ìtumõ keyboard n èlò àfôwôtç, dùrù kick n ìtàpá kick v tàpá kidnap v jí ènìyàn gbé, jí ènìyàn tà, jítà kidnapping n jíjí ènìyàn gbé, jíjínità, ìdánà kidney n iwe, ere, ôlô-inú kill v pa, gbé lëmìí killer n/f apànìyàn killer n/m apànìyàn kilo n kilo, òÿùwõn, ìwõn kilometer n ìwõn, ìjìnà kind adj (friendly) ÿènìyàn, nínú rere kind n (type) irù çgbë õwö kindness n ìÿeun, inú rere ôrç king n ôba kingdom n ìjôba ilé ôba ìlú kiss n ìfçnukonu kiss v fi çnu konu kitchen n ilé ìseþjç, ibi ìdáná kite n ohun ìÿeré tí a þ fi afëfë fë ní òfúrufú kitten n ômô ológbò, ômô ológìnní knead v pò knee n orúkún, ekún kneecap n egungun ekún kneel v kúnlê knife n õbç knight n irú olóyè kan knit v fi ôwö hun, dàpõ knob n kókó knock v lù, kàn, kànkùn knot n kókó, ìdìjú, ìsolù know v mõ know-how n ìmõ, ôgbön ìmõ, ìmõ iÿë ônà knowledge n ìmõ, mímõ, ôgbön êkö, òye knuckle n oríìké ìka, kókó ôwö Koran n Àlkùránì, ìwé-mímö Ìmàle |