pack v di çrù
package n çrù, èdìdì packing n palêmö, ìpalêmö, ìdi-çrù pact n àdéhùn, ìmùlë paddle n àjê paddle v wà-jê, ÿiré nínú omi page n ewé ìwé, akápò, ìránÿêkùnrin, aködà pain n ìrora, êdùn, rírí painful adj dídun-ni, níròjú, ìrora painless adj àìlëdùn, àìro, ÿàìní ìrora paint n tìróò, ajê, õdà, èsè paint v kùn, fi tìróò tàbí õdà kùn painter n/f afõdà kun, akun-õdà, akun-èsè, apödà painter n/m afõdà kun, akun-õdà, akun-èsè, apödà painting n ìkun-õdà, kíkun-õdà, àwòrán ôlödà pair n (people) ènìyàn méjì põ, tôkôtaya pair n (two) awë méjì palace n ààfin, ilé ôba pale adj (face) jíjorò, fúwöfúwö, rõndönrõndön palm n àtëlë ôwö, õpç palm tree n igi õpç pamper v kë, këra, jç àjçkì, fi oúnjç dídùn bö pamphlet n iwé kékeré aláìdìlù pan n àwo, páànù, ìkòkò paneling n igi ìbògiri inú yàrá panic n ìpààyà, ìdágìrì panther n àmõtëkùn, akátá pantry n ilé àwo oúnjç, yàrá tí à þ palê oúnjç mö sí pants n ÿòkòtò paper n ìwé, tákààdá paperclip n èlò ìdìmú ìwé parachute n agbòrùn ìbësílê láti inú ôkõ òfúrufú láìfarapa parade n ìtòlësê omô-ogun, àÿehàn, ìfihàn, fáàrí paradise n õrun rere, ôgbà dáradára onítura paragraph n gbólóhùn õrõ, orí õtò parallel adj tí ó jôra, tó ÿe dédé, lëgbêgbë paralysis n àìní-agbára, ààrún êgbà, àrùnkárùn tí þ gba okun ara paralyze v pasára, rô, sô-di òkú parasite n àfòmö, onírárà, apönni, ajçnirun-láìdáwó paratrooper n ômô ogun afagbòrùn bé sílê láti inú ôkõ òfúrufú parcel n èdìdì çrù kékeré pardon n ìdáríjì, ìfijì pardon v dáríjì parents n òbí, ôlömô parish n sàkání ìtöjú àlùfáà ìjô itún páríÿì park n ôgbà þlá fún ìtura gbogbo ènìyàn park v dá ôkõ dúró sí ojú kan parking n ìdá ôkõ dúró sí ojú kan parliament n àjô ôba, ìgbìmõ ôba parole n õrõ çnu, õrõ ôlá parrot n ayékòótö parsley n irú ohun õgbìn kan part n (piece) apá kan, ìpín, àràpa part v pín, ya, la irun orí partial adj àìpé, ti apá kan, ní ojúsàájú, ìÿègbé participant n/f oníbàpín participant n/m oníbàpín participate v bá-pín participation n ibápín particular adj pàtàkì, yç fún, àfiyèsíìdí particularly adv ní pàtàkì, pêlúpêlú, pàápàá partition n ìkélé, ìpín, ìlà partner n/f (business) alábàáÿiÿë, çnìkejì partner n/m (business) alábàáÿiÿë, çnìkejì partnership n àjùmõÿe, àjùmõÿepõ party n àjôyõ, çgbë, ôwö kan, apá kan pass n (mountain) õnà àárín òkè méjì pass n (permit) ìwé ìyõdà, ìwé ìwôlé, ìwé ìjáde, ìwé ìwõlú, ìwé ìjádelô pass v (travel) kôjá, wõlú, jáde ní ìlú pass out v dá kú, pín passage n (entrance) õnà àjò lójú omi passenger n/f èrò passenger n/m èrò passion n ìwà, ìtara, ìbínú, ìjìyà, ìjánu, inu ÿiÿó, inúfùfù passionate adj ÿónú, rúnú, ní inú-fùfù, nítara passive adj nírêlê, láìÿiÿë, pêlú sùúrù passport n ìwé ìyõdà ìwõlú tàbí ìjádelô password n kóòdù àwôlé, ìwörõfún, õrõ mímõ çnìkan ÿoÿo past adj kôjá past adj àtijö, níkçhìn past n (time) àtijô past (prep) (after) lëhìn pastime n ìdárayá, ìÿiré, fàájì pastor n oníwàásù, àlùfáà, olúÿöö-àgùntàn pastry n àkàrà pasture n pápá, oko tútù, koríko, ìjç çran pat v fi ôwö lù jëjë patch n êlê patch v fi aÿô túnÿe, lê patent n àÿç ìtösí nìkan patent v fihàn nígbangba paternal adj ti bàbá paternity n ti bàbá path n õnà, ípa-õnà patience n sùúrù, ìröjú, ìfôwöranú patient adj ní sùúrù, láìkánjú patient n/f aláìsàn patient n/m aláìsàn patriotic adj tí ó ní ìfë ilê nìtòótö patrol n olùÿö pattern n àpçrç, àwòÿç, àwòrán pause n ìdúró, ìdákë, ìsimi pave v fi òkúta të, rë pavement n (road) õnà olókúta, õnà ôlödà pavement n (sidewalk) õnà alámõ líle, õnà àfçsêrìn, õnà çlësê paw n èékánná çranko, ìkùkù pay n owó oÿùöyà pay v san-wó payable adj sísan payment n ìsanwó, àdásan payroll n ìwé ìsanwó òÿìÿë pea n pòpòndò, irú êwà òyìnbó kan peace n àlàáfíà, ìfàyà balê peaceful adj lálàáfíà, onísùúrù, onílàjà peach n irú èso kan peacock n çyç ológe, àgùfôn peak n orì òkè, ÿóþÿó peanut n êpà pear n irú èso kan pearl n òkúta iyebíye peasant n/f àgbê, aroko peasant n/m àgbê, aroko pebble n òkúta wërë pedal n çsê, ìfçsêtê pedestal n ìpìlê, çsê, ìgbélékè pedestrian n/f onírìnkiri, arìnkiri pedestrian n/m onírìnkiri, arìnkiri peel n èpo peel v bó, hó, bó lí èpo, bó bí awô peg n (hook) èèkàn, õgbágbá, ìgangan pelican n çyç ofú pelt n awô çran gbigbç tirun-tirun pelvis n ìbàdí pen n (write) kálámù penalize v jç níyà, báwí, ÿëníÿêë penalty n ìjìyà, ìÿçníÿêë, ìyà pencil n ohun èlò ìkõwé pending (prep) dúró dè pending adj tí à þ retí, láìlèÿeparí, tí þ bõ, àìtíìdé penetrate v wônú, làkôjá, làjá penguin n irú çyç kan penicillin n egbògi àpaàgùn peninsula n ilê tí omi fërëê yíkà penis n okó pension n owó ìsimi lënu iÿë, owó iÿë àÿesëhìn people n ènìyàn pepper n ata peppermint n efinrin ata ohun aláàdún tí þ ta ríyë per prep láti perceive v rí, fiyèsí, wòye percentage n ìpín lönà ôgörun perceptible adj tí ôgbön ìmõ perception n ìkíyèsí, ìrò, ôgbön ìmõ perceptive adj ní ôgbön ìÿe ìkíyèsí perfect adj pé, pípé, ànítán perfect v ÿe láÿepé, mú pé, ÿe tán perfection n pipe, ìÿepé, àìlábàwön, àìlábùkù perform v ÿe, mú-ÿe performance n ìÿe, ìmúÿe, eré, ìrôn performer n/f olùÿe, aÿiÿë, òÿeré performer n/m olùÿe, aÿiÿë, òÿeré perfume n òórùn dídùn perhaps adv bóyá perimeter n àgbègbè period n (grammar) àmí òpin period n (time) àkókò, ìgbà period n (woman) ñýkan oÿù, èélá periodic adj lêkànkan, nígbà ìgbà, lákòkò perjury n ìbúra èké permanent adj láìyçsê, láìlèyípadà permissible adj fún láàyè, taláÿç, ìgbàfún permission n àyè, ìbùnláyè, ìjëwö fún, ìyõõda permit n (certificate) ìwé ìfàyèfún permit v jê, bùn láàyè, yõõda, gbà fún persecute v ÿe inúnibíni sí, dálóró persecution n inúnibíni, ìdálóró, ìpönlójú persist v tçnumö, tçramöÿê, forítì, dìmú ÿinÿin, fi àáké körí persistence n ìtçramöÿë, ìforítì, ìdìmú ÿinÿin, jàgàdà persistent adj ní ìtçramö, ní jàgùdà pálí person n èniyàn, çnìkan, olúwarê, alámôrín personal adj nípa ti ènìyàn, ti ènìyàn personality n ìwà personnel n àwôn òÿìÿë perspective n ôgbön ìmõ wíwo-òkèrè perspiration n ìlàágùn, òógùn perspire v làágùn persuade v yí-lökàn padà, tàn, pa níyè dà persuasion n ìyípáda ôkàn, ìpaléròdà, õnà ìsìn ìgbàgbö, êtàn persuasive adj tí a lè yípadà pest n àrùn, ìyônu pet n (animal) çranko àyànfë, ohun-õsìn pet v fôwö ra-lára petal n ìrúdi títàn, ìtànná, òdòdó petition n (protest) ìtçnumö, ìkìlõ, êbê petrol n epo ôkõ pew n ìjóko nínú ilé Ôlörun pharmacist n/f elégbògi apo-egbògi pharmacist n/m elégbògi apo-egbògi pharmacy n ilé elégbògi phase n híhàn ojú òÿùpá, irí, ifarahàn apá kan philosophy n ìmõ, ôgbön, êkö ìmõ phonetics n pípe õrõ, fónëtíìkì phoney adj onírö, ohun ìdíbön, láìríbëê, ní ayédèrú photograph n àwòrán, fötò phrase n gbólóhùn, õrõ àpólà phrase book n ìwé gbólóhùn õrõ physical adj alágbára, ti agbára piano n dùrù àpáta pick n (tool) ôkö ìtúlê pick v (fruit) ká, ÿà, ÿàjô, já pickle n èso rírç sínú ôtí kíkan pickpocket n olè, jàgùdà, aláfôwöra, aláfôwöfë picture n àwòrán pie n irú oúnjç kan piece n êlà, apá, ìrépé, ìjàýjá, ègé, èbù pier n afárá pierce v wônú, gún, là-lô pig n çlëdê pigeon n çyçlé pigment n àwõ, ìrí pile n (wood) ìkóga pilgrim n/f èrò mímö alárìnkiri, olùbêwò ibi mímö pilgrim n/m èrò mímö alárìnkiri, olùbêwò ibi mímö pilgrimage n ìrìn àjò èrò mímö, ìbêwò ibi mímö pill n egbògi, ìÿù ògùn pillar n òpó, ôwön pillow n ìrõrí, tì¸tì¸ pilot n atukõ, afõnàhàn nínú okõ, atukõ bàlúù pimple n èsúsú ara, rorë pin n èékán, èlò ìsopõ aÿô, èlò àsopõ pinch n ìjálékánná pinch v já lékánná, ÿún pine n orúkô igi kan pineapple n öpç òyìnbó pink adj àwõ pupa fërë pioneer n aÿájú, alànàsílê pipe n ikòkò tábà, fèrè pirate n ajalèlókun pistol n ìbôn ìléwô piston n èlò onírin gígùn kan pit n kòtò, õfìn, ihò pitchfork n ôkö ìdáko, ohun èlò ìdáko, èlò ìhúlê pitiful adj láànú, kún fún ìyönú pity n áànú, ìyönú place n ìbì, ipò, àyè place v fi síbì kan, fi-sílê, gbékalê, gbélé plague n ìyônu, àjàkálê àrùn plain adv õbõrö, tëjú, möjú plaintiff n/f olúfisìn, asunni plaintiff n/m olúfisìn, asunni plan n èrò, àpçrç, àwòrán tàbí àpçrç kíkö ilé plan v wé iÿë, wé èwé planet n ìràwõ tí þ yí oòrùn ká planning n wíwé iÿë, wíwé èwé plant n (factory) ilé iÿë, ilé òwò, ibití a tí nÿe ohun títà plant n (object) ewéko, ewébê, ohun õgbìn plant v gbìn, lö, ÿàgbê plaster n çfun, erùpê ìÿánlé, aÿô ológùn fún bíbò egbò plastic adj ÿìÿù plastic n ìÿìÿù plate n àwo pçrçsç platform n (stage) pçpç, pákó ìdúrólé, ìtàgé platform n (train) pçpç ìtêgùn ôkõ, ilêwô ôkõ ilê play n eré, iré ÿíÿe, fádà play v ÿiré, tê, lù player n/f eléré, atçdùrù player n/m eléré, atçdùrù playful adj kún fún iré ÿíÿe, láyõ, inú dídùn playground n ibi ìÿiré plead v (law) bêbê fún, tôrô ìdáríjì, gbçjörò pleasant adj dùn, wù, ayö, jôjú please v wù, ÿe inúdídùn sí, dùn mö, wúni-lórí, jõwö, jàre please adv dùn, wù pleasing adj fuyì, wíwù, tí wúni lórí, tí dùn möni pleasure n inú dídùn, fàájì êwùn, ìfë pledge n ògo, ohun êrí, ìpinnu, májêmú pledge v gbà logo, ÿe ìgbõwö plentiful adj õpõlôpõ pliers n êmú kékeré plot n (land) ilç bíírí plow n ôkõ ìtúlê plow v túlê pluck v (fruit) já ká plug n (electric) ohun èlò ìtanná plug n (sink) èdídí, ìdënu plug v dídì çnu õkan plum n èso kan bí ìyeyè plumber n oníÿë àtúnÿe êrô omi, oníÿë ìdênu plural adj õpõ, ìlöpo méji plus prep ìfikún, pêlú pneumonia n àrùn êdõfóró pocket n àpò êwù poem n ìwé akéwì, orin, õrõ orin poet n/f akéwì, onírárà poet n/m akéwì, onírárà poetry n ewì, ìwé olóÿùwõn, ìwé çsçsç orin point n (game) ìÿirò, iye point n (location) ìtökasí, ìfõnàhàn point n (number) iye point n (thought) ìdënulé, àfìyèsí, ohun tí a þ jiyàn lé lórí point n (time) ìgbà point n (tip) ojú, ÿónÿó, ténté point v töka-sí, sàmì sí, fõnàhàn pointless adj láìnídìí, láìlètökasí poison n oró, iwô, májèlé poisoning n sísô lóògùn, fifun ni májèlé, dídánilóró poisonous adj olóró, lóró, iwô ti þ pani poke v bì, tì, táràrà, gún polar bear n çranko þlá aláwõ funfun tí þ gbé ìkángun ilê àríwá pole n õpá, òpó police n àwôn ôlöpàá police station n ilé iÿë àwôn ôlöpàá policeman n ôlöpàá policewoman n ôlöpàá policy n (manner) oyè iÿë ìtöjú ìlú ètò ÿíÿe ètò aláÿç polish v dàn, lõ polite adj níwà rere politely adv tõwõtõwõ | political adj ti àkóso, nípa ìÿèlú
politics n ìÿèlú, oyé ìÿìÿé àkóso ìlú, ôgbön ìÿèlú, õràn ílú poll n orí, ìwé orúkô àwôn ará ìlú pollute v bà-jë, sô di àìmö pollution n ìbàjë, àìmö, èérí pond n omi ìkúdú, àbàtà, õgõdõ pony n çÿin kékeré, kùùrú pool n (swim) adágún, ìkùdu, adágún ìlúwêë poor adj tálákà, aláìní, alábòsí, òtòÿì, alábùkù poorly adv bíi tálákà, aláìní pope n olórí êsìn ti ènìyàn gbogbo, olórí ìjô kátólíkì popular adj lókìkí, lásìkí, tí a lé yë sí, tí àwôn ènìyàn ní inù dídùn sí population n iye aráàlú ìlú kan porcelain n amõ tí a fi þ mô àwo porch n ìloro pork n çran çlëdê pornography n àwòrán ìwòkuwò, àwòrán ìhòhò ènìyàn gedegbe fún ìmúni lára yá porpoise n çran esé port n èbúté, ibi ìgúnlê sí, ibi ìdákõró portable adj rírù, gbígbé, ÿeé gbérù, ÿeé gbé fërë porter n/f oníbodè, olùÿönà, aláàrúù, olùdènà porter n/m oníbodè, olùÿönà, aláàrúù, olùdènà porthole n fèrèsé ôkõ ojú-omi portion n (piece) apá kan, ìpín, àràpa portray v fihàn, yà, júwe pose n ìdúró àìyçra nìwájú ayàwòrán position n ipò positive adj ÿaláìyíhùn padà, dájú possess v gbà, ní, jogún possession n ìní, ohun ìní possibility n lílèÿe, lílè rí bëê, àfàìmõ possible adj ní ÿíÿç, tí ó lè ÿe, lágbára ÿíÿe possibly adv ÿeéÿe, bólèÿepé, bólèÿebí, bóyá, bôyá post n (position) ibi iÿë post n (wood) òpó ilé post card n ìwé àwòrán tí a fi þ kô lëtà post office n ilé ìfìwé ránÿë postage n owo ìfìwé ránÿë postbox n àpótí ìfigba ìwé ìránÿë poster n ìwé àwòrán þlá, àwòrán þlá ìpolówó ôjà postman n apínwékiri postmark n àmì ìfìwé ránÿë postpone v dá dúró, fà-sëhìn, yô-sëhìn postponement n ìdádúró, ìfà-sëhìn, ìyô-sëhìn posture n ìpò, ìwà, àyè, ìdúró pot n ìkòkò, apç, ìÿasùn, ìÿà potato n kúkúýdùkú, õdùkún, ànàmö potent adj lágbára, ní àÿç potential n ágbára àtiÿe, ojúÿe, aÿeéÿe, lílè mú ÿç, okun pottery n çbu, ìkòkò mímô poultry n adìyç sísìn pound n (animal) àgbò çran tí ó ti ÿáko pound n (weight) òÿùwõn pound v gún sí wëwë, gún põ, lù, fêÿëlù pour v tú, dà jáde, dà poverty n àìní, òÿì tálákà ìhálé ìÿë ìtúlêjç powder n çtù, çtù ìbôn power n agbára, ipá, àÿç powerful adj lágbára, nípá, ní àÿç powerless adj láiílágbára, láìnípá practical adj wúlò practice n ìÿe, ìlò, ìwà practice v ÿe, lò, hùwà prairie n pápá, koríko gbígbç praise n iyìn, ìyìn lógo praise v yìn, fi ìyìn fún pray v gbàdúrà, bêbê, tôrô, kírun prayer n àdúrà, êbê, ìtôrô, ìkírun, ìbêbê preach v wàásù precaution n ìtètè fura, ìtètè kíyèsí, láìkáàbámõ precede v ÿaájú precedent n àpçrç, ìÿájú, ìÿe bëê rí precious adj iyebíye, níyelórí, ojúlówó precise adj lákòkò gan-an, kóngë, gë, gbáko precision n dédé, gëgë, ìgbà gan-an precondition n ìÿe sájú, ìbêrê ñýkan predecessor n ará-wájú, aÿájú çni nínú oyè predict v sôtëlê, wítëlê, sô àwítëlê, fura predictable adj tí a lè sô tëlê, ìfura predominant adj wöpõ, tayô, borí preface n õrõ ìtúmõ ìÿájú ìwé prefer v yàn, fi ÿájú, bu iyìn fún, fë jù, fi sípò preferable adj yíyàn, dára jù preference n ìbuyìnfún, ìfiÿájú, ìfëjù, ìfisípò prefix n ìfiÿájú pregnancy n oyún pregnant adj lóyún, ní ôgbön, kún fún prejudice n èrò búburú sénìyàn, láìnídìí, àìnífêësí nítorí íran tàbí àwõ ara preliminary adj ti ìÿájú, ti ìpilêÿê premarital adj ètò ìÿájú ìgbeyàwó premature adj ÿájú àkókò, yá jù, láìgbó, láìpön premises n ilé, ilê, àyíká ilê premium n èrè, ojúlówó premonition n ìkìlõ tàbí àmì ñýkàn tí þ bõ, ìfura, àwítëlê prepaid adj owó àsansílê preparation n ìmúra sílê, ìpèsèsílê, ìpalêmö prepare v pèsè, múra, tëlê, palêmö preposition n õrõ atökùn prerequisite n ohun ìÿájú ñýkan prescribe v fi àÿç fún, lànà, júwèé, kô egbògi fún prescription n ìwé ìlànà egbògi presence n ojú çni, ìwà níbìkan present adj nísisìyí, löwölöwö, lójúkójú present n (gift) êbùn, ôrç present v fi fún, gbé kalê níwájú, ta lörç presentable adj tí ó ÿeé wò, tí ó ní lárí presentation n õrõ sísô nínú àkójô presently adv löwölöwö, lójúkójú preservation n ìpamö, ítöjú preservative n ohun ìÿöra, ìÿörí, èlò ohun àjçsàra preserve v pa mö, ÿe ìtöjú presidency n ipò alákoso, ipò olórí president n alákoso, olórí press n (news) àwôn oníròhìn press v (push) tê, rölù, fún, sú mö pressing n ohun tí ó fë ìfojúsí ní kíákíá pressure n ìkìmölê, títê, fífún prestige n agbára, ìwà, ôrõ presume v kùgbù, gbàgbö láìwádìí presumption n ìkùgbù, ìgbëkêlé ñýkàn áìdánilóju, ìdágbálé pretend v ÿe bí çnipé pretty adj lëwà, dára prevail v borí, ÿëgun prevent v dí löwö, dí lönà, kálöwö prevention n ìdádúró, ìdálöwökö, ìdílöwö preventive adj ní agbára ìdádúró, ìdálöwökö preview n àköwò previous adj ti ìÿáájú prey n ìkógun, ohun ôdç price n iye, owó-õyà, ìkúnlójú, ímô-rírì iye owó ôjá priceless adj láìlèdíyelé, láìníyelórí pricelist n ìwé ìdíyelé pride n ìrera, ìgbéraga priest n àlùfáà primarily adv ní patakì jùlô primary adj nípò èkíní, olórí, pàtàkì primary school n ilé êkö kékeré prime minister n olórí, alókoso primitive adj ti ìbêrê, ti ìgbà àtijö, ti àtètèköÿe, ará oko prince n ômô ôba, ômô aládé princess n ômô-bìnrin ôba, ômô-bìnrin aládé principal adj ní pàtàkì, olórí principal n (school) olórí ilé êkö principality n àwôn ìjòyè ilê ômô ôba agbára ôba principle n ìpilêÿê êkö, òfin ìpilê print n àmì, ìwé títê print v tê, sàmì sí printer n (machine) êrô ìtêwé printing n ìwé títê prior adj ÿaájú, tì ìÿájú, titëlê priority n pàtàkì jùlô prison n ilé êwõn, túbú prisoner n/f çlëwõn, ará túbú, oþdè prisoner n/m çlëwõn, ará túbú, oþdè privacy n ibi ìkõkõ, ibi ìpamö, kölöfín private adj ìkõkõ, ìfarapamö, abele, àÿírí privilege n àýfàní, ôlá prize n èrè, êbùn probability n bóyá, jíjô, bí çnipé probable adj tí a lè dánwò, tí a lè rídìí, àfàìmõ probably adv bóyá, àfàìmõ probation n (job) àkókò ìdánwò, ìgbà àkököwôÿë probation n (law) ìdánwò problem n ìÿòro, ohun àyêwò procedure n ìtësíwájú ìrìn, õnà tí à þ gbà ÿe ñýkan, ìÿiÿë, ìlànà proceed v têsíwájú, ýÿó, lô síwájú, ÿe, mabálô proceedings n ìkójô ìÿçlê ìpàdé, ìÿçlê ìpàdé àkójôpõ process n ìgbésê, õnà process v gbésê processing n gbígbésê proclaim v kéde, sô nígbañgba, poloñgo procrastinate v dá dúró, fàsëhìn, ÿàìÿe lásìkò, fòní dónìí-fõla-döla, fi falê produce v mú ÿç, bí, so, hù producer n atökùn product n èhù, òpin iÿë production n ìmúwá, ìbísi production line n iÿë ôwö àpéjô òÿìÿë productive adj eléso, ôlöràá, lágbára ìmúwá tàbí ìbísi, ÿe pàtàkì, nílárí productivity n ìmúwá, ìbísi profession n ìjêwö, ìpè, iÿë professional adj nípa ti iÿë professional n (business) òÿìÿë professor n/f olùkö ilé ìwé gíga, õjõgbön professor n/m olùkö ilé ìwé gíga, õjõgbön proficient adj yìyç, títö, pípé profile n àwòrán orí tàbí ojú, ìkójô ìwífúnní nípa ènìyàn profit n èrè, àýfàní profit v jèrè profitable adj lérè, làýfàní, níbùkún prognosis n ìmõtëlê, ìsôtëlê program n ìwé ètò ohun tí a o ÿe ní ìpàdé ìwé iÿë progress n ìtêsíwájú, ìlôsíwájú, ôláþrewájú progressive adj nílôsíwájú, nítêsíwájú prohibit v kõ fún, dá-dúró, kálöwö, ÿòfin, dí lönà, dá lêkun prohibition n ìkõfún, ìdá-dúró, ìdínà, ìdálëkun, èwõ ìÿòfin project n ìrò, ìgbèrò projection n (estimate) ìkaye, ìÿirò, ìdíyelé prolong v fà gùn, mú pë, dúró títí, falê promenade n ìgbafëfë, õnà àfçsêrìn ní gbangba prominent adj yôrí, hàn kete-kete, lókìkí promise n ìlérí promise v ÿe ìlérí promote v (person) gbé-ga gbélékè sún síwájú promote v (product) polówó promotion n (person) ìsúnsíwájú, ìtêÿíwájú, ìgbélékè promotion n (product) ìpolówó prompt adj múra, kankan, ÿetán, láìdára dúró prompt adv ní tanijí pronoun n àröpò orúkô pronounce v pè, ÿõrõ pronunciation n ìpè, pípè, ìsõrõ proof n àmì, êrí, ìmúdánilójú propaganda n õnà ìtànkálê propeller n àjç-ôkõ proper adj yç, tö, dára property n ohun ìní, ìtösí prophesy n ìsôtëlê, àsôtëlê, ìwítëlê, àwítëlê prophet n alásôtëlê, aláwítëlê, wòólì, wòlíì, aríran proportion n ipò onírúruú ñýkan sí ara wôn, òÿùwõn ôgbôgbà proposal n ìdámõràn, ìmõràn, àbá, ìfiyèsí propose v dá-mõràn, fiyèsí, dá lábàá, pèrò proposition n ìfiyèsí, ìdálábà, ìdámöràn, ìmöràn prosecute v lépa, bá rojö, pè lëjö prosecution n ìbárojö prosecutor n abánirojö prospect n àfojúsönà, híhàn, ìwò, ìrì, ìrètí ohun rere prosper v ÿe rere, ÿe ásìkí, lô dédé fún prosperity n àláfíà, ásìkí, ajé prosperous adj tí ó rege, alásìkí, níbùkún, alájé prostitute n pañÿágà obìnrin, àgbèrè, õdökô, kárúwà protect v dábòbò, bò, gbèjà protection n ààbò protective adj ti àbò, lábò protector n (object) alábò, olùgbèjà protector n (person) alábò, olùgbèjà protest n ìtçnumö, ìkìlõ, ìkédèe protest v tçnumö kìlõ protestor n/f akédèe, alátçnumö protestor n/m akédèe, alátçnumö proud adj nígberaga, onígberaga, láìnítçríba prove v dánwò, rídìí, làdì, fihàn proverb n òwe provide v pèsè sílê, pèsè fún, múwá, fihàn province n ìgbèríko, ojú iÿë provincial adj ti agbègbè ìlú provisional adj tí a pèsè tëlê provisions n (supply) èsè, ìpèsè tëlê provocative adj ti imúnibínú, nípa títö, oníyônu provoke v tö, mú bínú, rú sókè, yô lóhùn, yô lënu, fìtínà proximity n agbègbè, ìtòsí, etí psychiatrist n/f oníwòsàn aÿiwèrè psychiatrist n/m oníwòsàn aÿiwèrè psychological adj nipa ti ôkàn àti ìwà híhù pub n ilé ôtí, ilé ìmutí puberty n àkókò èwe ôkùnrin tàbí obìnrin public adj ti gbogbo ènìyàn, mímõ fún gbogbo ènìyàn publication n ìkéde, ìtêwé sóde, ìtúkáàkiri, ìfilõ publicity n ìkéde, ìfilõ publicize v ÿô di mímõ, polówó, kéde publish v sô di mímõ, kéde, filõ, tç ìwé fún títà, wí kiri publisher n aÿèwétà, atêwétà publishing n ìsô di mímõ, ìkéde, ìÿèwétà, ìtêwétà puddle n õgõdõ kékeré, kòtò kékeré pull v fà pulley n êrô ìfà ohun wúwo sókè pulpit n àga ìdúró wàásù pulse n ìlù kìkì ôkàn, êwa ìsôkúlú, ìsôkúlú igbá-àyà pump n êrô ìfa omi láti kànga pump v fà sókè, fà sínú, fë afëfë sí pumpkin n elégede punctual adj ÿe lákókò, ÿe punctuation n àmì inú ìwé kíkà, ìfàmìsí puncture n ihò kékeré punish v jç níyà, ÿë níÿêë punishment n ìyà, ìjìyà, ìjçníyà pupil n (eye) inú çyin ojú, ilà ojú pupil n/f (student) ômô ilé ìwé, akëkõö, ômô-iÿë pupil n/m (student) ômô ilé ìwé, akëkõö, ômô-iÿë puppet n ÿìgìdì, àdìmókùn, ômô lañgidi àdìmókùn puppy n ômô ajá purchase v rà pure adj mö, dá ÿáká, funfun, ní ìwà àìlábàwön, àìlábùkù purple adj àwõ àlùkò, elésè àlùkò purpose n (reason) èrò, ohun tí þ lépa, èrèdí purposeful adj ti àýfàní, tí o ní ìpinnu purse n àpò owó pursue v lépa, sáré lé pursuit n ìlépa, ìtêlé pus n ôyún push n ìtari, ìsögô síwájú push v tì, bì, rö, tari, sögô pushy adj bç, abçbçlúbç put v fi sí, fi lé puzzle n ìÿòro, ìÿújú, ìrújú, ohun gígö, eré ìrújú puzzling adj rírújú, ìrúnilójú, alálõö àpamõ pyjamas n aÿô àwõsùn pyramid n ìsà òkú ôba àwôn ará Égíptì |