cabbage n êfö òyìnbó
cabin cabin n yàrá inú ôkõ, yàrá, àgö cabinet n (government) ìgbìmõ ìjôba cabinet n (storage)àpótí ohun öÿô cable cable n okùn tàbí ëwön ìdákö dúró cactus n igi ôrô cadet n/f àbúrò akêëkô ní ilé ëkô ômô-ogun cadet n/m àbúrò akêëkô ní ilé ëkô ômô-ogun café n ilé ìjçun caffeine n èlò kíkorò inú obì, èlò ìmu kánilára, èlò ìrúsókè ara cage cage n ilé çyç, àgö kuku cajole cake cake n akara didun oyinbo ole moinmoin calabash calamity calcium n ògùn ìmún egungun lágbáraohun éló pàtàkì tí mbç nínú ilë calculate calculate v ÿírò, kà calculation n ìÿirò, kíkà calculator n ërô ìÿirò calendar n ìwé ìkaye oÿù/õsê/àti ôjö nínú ôdún calf calf n (animal) ômô màlúù, ogodo calf n (leg) iÿu çsê call calm call n (contact) ìpè call v (contact) pè call v (name) pè call v (telephone) tê lágogo, na ohùn sí call n (telephone)bíbásörö lórí ërôpípè lórí ërô ìsörögbésì callous calm (adj) ìdákê íparôrô ìrölè calm v rôlëdákê calmness n ìdákêjêjêìdákê rôrô calorie n ìwön ìfúni lágbára àti ànfàní inú onjç camel n ràkùnmíibakasie camera n ërô ìyàwòrán camouflage (v)farapamôbadeni camouflage n ìfarapamôabadeni camp n ibùdó, bùdó, àgö camp v dó, bùdó campaign n papa nlaìgbà ogunÿá ogunÿá ötë campsite n ibùdó, àgö campus n ôgbàôgbà nlá ilé ìwé can can v (allow) lè can n agolo, páánú, tanganran can opener n ërô tàbí öbç ìÿí agolo can v (able)lè ÿelèlágbára canal n odó lílà cancel v nù-kúròpa-ré cancellation n ìparêìnùkúròìsôdòfo cancer n akanalakasaàrùn búburú kan candid (adj)dájúlótítôláìÿëtánlódodo candidate n/f ênití nfê wô inú çgbê tàbí iÿê candidate n/m ênití nfê wô inú çgbê tàbí iÿê candle n àbëlà, fìtílà candy n ohun àdídùn cane n ôparun canister n agolo, páànù cannibal n ajênìyàn cannibalism n jíjç ènìàìwà jíjç ènìyàn cannon n ìbôn nlààgbá canoe n ôkö ôkö wétèìgbájá canoe v wa-ôköwakö canopy n àtíbàbàìboríaÿô tí a ta sórí ìbùsùn canteen n (water)agolo kékeré ìrômisíagolo ìrômisí àwôn ômô ológun canvas n (cloth)aÿô aláìkúnáìgbòkun canvas n (painting)ìgbòkun ìkun àwòrán canyon n ilë jíjìn láarín òkè méjì cap n (cover) ìderí cap n (hat) fìlà, ìborí cap n (lid) ìderíômôrí capability (n)agbáraàyè capable adj toìlèÿelágbáralóyenípá capacity (n)agbáraipáàyè cape n (area) ÿónÿó ilê tí ó yôrí sínú omi cape n (clothing)ìlékè aÿoìpèléëwù èjìká capital n (city)olóríilë olórí ìjôba ìlù ôbaolú ìlú capital n (money)òkòwòowó-ìlélë capitalism n nípa ÿíÿe òwòohun òkòwö capitalist n/f olówó, ôlörõ capitalist n/m olówó, ôlörõ capitulate (v) jölôwô lêhìn àdéhùntúnbá pëlú àjôsô capsize v dojúbolëri ôködojúdéyípo captain n olórí çgbêögáköögágunbalógun captive adj ìgbèkùn, ondè, çlêwön captive n/f çrú, çlêwön captive n/m çrú, çlêwön captivity n oko-çrú, ìkólërú capture v mú lêrúfi agbára mú car n ôkö aláfêkëkêmôtò òrénté caravan n (vehicle) çgbê ôkö aláfê carbon n èkuru dúdú inú ilëèfín dúdú tí yô ní ìdí môtò carburettor n ërô tí mú ôkö rìnërôìdákörìn carcass n òkú ènìàòkú çran card n ìwé pçlçbç káàdì cardboard n páálí care n ìtöjú, àbójútó, aájò, àníyàn career n iÿé ìgbé ayé carefree adj láìníyàn careful adj kún fún àníyànÿôra careless adj aláìníyàn àìbìkítà aláfara àìfarabalë wàdùwàdù carelessness n áfaraàìbìkítààìwolë caress n ìfàmôraìkêìgbàmôraìfôwôpalára caress v fàmôrakíkêgbà-môrafôwô-palára cargo n çrù ôkö carnage n ìwôpö òkú ènìàìpakúpaìpànìà púpö lógun carnation n irú òdòdó kan carnival n ibi ôjà ìdárayá carp n ìjiyànìríwísíìbáwíirú çja kan carpenter n gbênàgbênà, oníÿônà igi, afági carpentry n iÿê igiiÿë gbênàgbênà carpet n aÿô wúwo ìtêsílëaÿô ìbùsùn carriage n këkê çlêÿinìwà ìÿesí carriageway n önà têrê këkê çlêÿin carrier n (disease)kòkòrò tí nmú àrùn tàn carrot n ohun ògbìn kan carry v gbé rùpönkó cart n këkê çrù çlêsë méjì cartilage n òkérékèré carton n pálí cartoon n àwòrán àrofö cartridge n àpótí ôta ìbôn carve v gbêfínkun carving n gbìgbêgilérekíkunfífínohun fífín case n (box) àpótíàkö case n (law) çjôìbáwíjô cash n owó cash v ÿê-owólo ipò cashier n/f onítôjú owóaköwé tí nsan owó cashier n/m onítôjú owóaköwé tí nsan owó casino n gbàngàn tëtë casket n pósíàpótí kékeré cast v (metal) dá àgbëdç castle n ààfinilé ìÿô castrate v të ní ödátë ní bààfin casual adj alábàápàdéàìronú têlë casualty n/f çní farapaçní kú lójú ìjà casualty n/m çní farapaçní kú lójú ìjà cat n ológìnní, ológbò catalog n ìwé orúkôìwé ìpolówó ôjà catastrophe (n)ìparí àìdáraàyàlùìjàmbáòpin örànwàhálà catch v mú dá-dúrórámúhángán category n êyà cater v pèsè onjç caterpillar n öökùnkòkòrò cathedral n ilé ìjôsìn nlá Catholic adj ësìn ti ènìà gbogboti àgbáiyéti ìjô Àgùdà Catholic n/f onígbàgbô ësìn ti ènìà gbogbo Catholic n/m onígbàgbô ësìn ti ènìà gbogbo cattle n çran ösìn cauliflower (n)ohun ögbìn òyìnbó kan cause n ìdí, ìtorí cause v dá sílëmú ÿebá wá caution n ìwòyeôgbônàkíyèsíìkílöìÿílétíësö cautious adj níÿôraníwòye cavalry n ogun çlêÿin cave n ihò nínú àpátaihò inú ilë cavern n ihò nísàlë ilë cavity n (tooth) ihò inú ehín cease v dáwôdúrówawôÿíwôdá dêkundàböyé cedar n igi òpepe ceiling n òkè àjààjà ilé celebrate v ÿèrántíkókìkíÿôdún nkanÿènáwó celebration (n)ayçyç ìnáwóìyìn ìrántíàÿà celery n ohun ögbìn òyìnbó kan celibacy n wíwà ní àpônàìyígbéyàwóÿíÿapôn cell n (body) êyà-ara cell n (prison) ôgbà êwõn cellar n yàrá ísàlë iléibi àpamô nkan nísàlë ilé cement n amö líle cemetery n ìtê òkúibi ìsìnkúìtê censor n ìbáwí censorship n ìbáwí censure v bá-wí census n kíkaye ènìà ìlú center n àárínagbedeméjì centimeter n irú ìwön kan centipede n öökùntani-ÿánko central adj láarínlágbedeméjì centralize v ÿe sí àárínfi sí agbedeméjì century n ôgôrun ôdún ceramic adj ohun èlò amö cereal n irú oúnjç àárö kan ceremonial (adj) ÿíÿe àpéjôÿíÿe ìsìn ceremony n ìÿe ìsìnàmì òde ti ìsìnato certain adj dájú certainly (adv)dájú-dájúláìsí àníànínítòótôdandan certainty n ìdánilójúàìÿiyèméjì certificate n ìwé èríohun ërí certification n íjêërísí certify v jêëríròhìnmú dájú chain n êwõn chain reaction n ìkôlura-àdëhìnbö chair n ágaìjoökó chairman n aláàga, olórí àjô, olórí àpéjô chalk n çfun challenge n ìpèníjàìfìjàlöìtôniníjàìfòláyà challenger n/f olùpeniníjàapeniníjà challenger n/m olùpeniníjàapeniníjà challenging adj tí npèníjàtí nfì jàlö chamber n iyàráìyëwù champagne n n orúkô ôtí líle kan champion n/f ögágunoníÿêgunató-pa-lôtöaÿájú ìjà champion n/m ögágunonisegunato-pa-lotoasaju ija championship (n)ìÿe ögágunÿíÿe aÿájú ìjà chance n àyè alábàápàdéèsì akôsëbáarìnkò chancellor n aÿíwájúolórí ilé-ëkô gígaaköwé nílé çjôamòfin change n (money)pàrö owóìpàrö change n) (alteration)ìyípadàìparadà change v (alter)yípadàparadà change v (money) ÿê-owópàrö changeable adj ti nyípadàtí nÿe pàÿípàrö channel n (television)ërô àwörántçlefísön channel n (water) ìsàlë odò chaos n ìdàrúdàpötëmbëlëkúnjúujùu chaotic adj ní rúdurùdu chapel n ilé Ôlörun kékeré chaplain n oníwàásù ní ilé Ôlôrunoníwàásù çgbê àwôn ômô-ogun chapter n (book)orí ìwéìpín ìwé character n/f (person)ìwàorúkôènìà character n/m (person)ìwàorúkôènìà characteristic adj ti ìwà charcoal n èédú igi charge n (expense)ìdíyeléìnákúnàá charge n (law) ësùnìlöìfisùn charge v (battery)fún-lágbára charge v (expense)díyeléÿe ìnákúnàá charge v (law)kà sí lôrùnfisùn charge v (military)ìpàÿç fún charity n ìfêniôrç-àánúìyônuohun-ôrç charm n òògùn oñdètíràògèdèìfàyà charming adj nífàyànífaláyàtí ó wu ni chart n ìwé àwòrán àpçrç charter (v)háyà chase v lépa chat n ìrégbèìbásörö chat v bá-söröwírèégbè chauffeur n òÿìÿê tí nwa ôkö ayôkêlêawôködírêbà cheap adj pöwôpöàìwônàìníyelórí cheat v rë-jç, yànjç, tàn-jç check n (control)ìdádúróìkíwô check n (money)iwe ìgbowó ní bánkì check v dá-dúrókí-wô checkpoint n ibi ìdánidúró lêëbá önà checkup n àtúnwòàtúnyëwò cheek n êrêkë cheer n ìmúninínúdùnayöìtúraká cheer v gbà-níyànjúmútújúkámúnínúdùnmúlárayá cheerful adj dídárayátújúkálôyàyà cheese n wàràkàsì cheetah n çranko ìgbê kan chef n/f çnití tí nÿe oúnjç fún àgbájôolónjç chef n/m çnití tí nÿe oúnjç fún àgbájôolónjç chemical adj ti èlò àfôgbôn dá chemical n èlò ìpìlë tí a fi nmú ohun míràn jáde chemist n/f apògùn elégbògi chemist n/m apògùn elégbògi chemistry (n)irú ëkô kan cherry n irú èso òyìnbó kan chess n irú eré kan tí àñta lórí ôpôn chest n (body) àyà, ìgê chest n (box)àpótí chew v fi ehín rúnrún lênujç chewing gum (n)ohun ìpanu aládùn chicken n adìyç, ômô adìyç chickenpox (n) ôfà ÿöpönnáilëgbôná chief n (leader)aÿíwájúolórí olúögáalákòóso chief n (tribe)olórí olóyè pàtàkì chiefly adj ní pàtàkì child n ômô, èwe, ômôdé childbirth n ìbímô childhood n àkókò ômôdéìgbà èwe childish adj ìÿe ômôdébí ômôdébí èwe chimney n ihò èéfín chimpanzee n irú öbô kan chin n ìgbön, àgbön china n àwo alámöohun èlò tí a fi amö ÿe China n ìlú ilê àwôn Sainí chip n (glass)ërún wíníwíní chip n (rock)ërún òkúta chip n (wood)ërún igi chip v (wood) ÿe êrún igigé igi sí wêwê chisel n ohun èlò onírin tí a fi ngbê igi chocolate n kòkó lílö tí a fí ñpanu choice n yíyànàÿàyànayò choir n çgbë akôrin choke v fún lôrùnhá lôfun cholera n irú àrùn kankôlêrà choose v yàn ÿà chop v gé wêwêgé pópòpó choppy adj àìdán chopsticks (n) igi àgúnjç chord n (music)okùn dùrù chorus n çgbê orin (ègbè orin) Christ n Krístì Christian n/f onígbàgbô ësìn ti enìà gbogboômô-ëhìn Krístì Christian n/m onígbàgbô ësìn ti enìà gbogboômô-ëhìn Krístì Christianity n ìsìn Krístì Christmas n ôjö ìbí Krístì chronic adj pípê títídi àrùndi bárakú chronicle n ìwé ìtànìròhìn chronological (adj)lêsçsç chunk n ìÿù church n ilé ìjôsìn ilé Ôlörunìjô onígbàgbô churchyard n ôgbà ilé ìjôsìn chute n ihò alágolo nlá cigar n tábà, sìgá cigarette n tábà inú ewésìgá cinema n àwòrán tí nrìnilé àwòrán tí nrìn cinnamon n èso igi gbígbç olórùn fírínfírín kan circle v yíká circle n àyíkáòrùkaòbìrìkìtì circuit n ìyíká circular adj bí òbìrìkìtìkibitikiribiti circulate v tàn-yíkàmú yí káà kirirìn yíkárò yíká circulation n (body)ìÿànyíkàÿíÿàn ëjë yíkà ara circumcise v kônílà kôlà-fúndákó-fún circumference (n)ìyíká circumstances (n)örànohun ÿíÿë circumstantial adj ní alábáápàdéìfihàn kíníkíní nípa bí nkan ti lô sí circus n ibi eré ìdárayá tí àwôn çranko ñpidán citation n (ticket)ìwé ìkìlö cite v (law)pò-fin citizen n/f ará ìlúonílùúaráalë citizen n/m ará ìlúonílùúaráalë citizenship n nípa ará ìlúdídi ará ìlú city hall n gbàngàn ìdájôgbàngàn ìlúìtê ìjôba city n ìlú, ìlú nlá civil rights n ëtô sí ènìàìlòsí ènìàìwà ìmô-ëyç sí ènìà civil servant n/f oníÿê ìjôba civil servant n/m oníÿê ìjôba civil service (n) iÿê ìlú civil war n ìjà abêlëìjà-ìlúìjà ìgboro civilian n ará ìlú civilization (n)ìlàjú civilized adj õlàjú claim n (law)ìbéèrè ohun tí ìÿé tçni claim v (law)béèrè ohun tí ìÿé tçni claimant n/f çnití ó pe nkan ní tirë claimant n/m çnití ó pe nkan ní tirë clam n irú ìgbín kanìgbín ösà aláìníkarahun clamp n oñdè onírin clamp v dè-môle clan n ìdílé, ëyà clap v pàtëwö clap n ìró àtêwô clapping n pípàtêwô clarification (n)ìsôdi mímöìÿelàjúÿíÿe àlàyé clarify v ÿàlàyésôdi mímömú kí ó mö clarity n dídá ÿákáÿáká clash (v)kô-lura clasp n dìmú ÿinÿinìdìmúìkóìwö class v tò lësç class n (type)çgbê classical adj tí ó lêgbétí çlêgbê gíga classification (n)ìtò lêgbçgbêìtò lôwöôwô classify v ÿe létò létòtò lêgbçgbêtò lôwöôwô clause n gbólóhùnörö kan claw n èkánná çsë çiyç tàbí çranko clay n amö clean v wê-mö clean adj àìní àbawönmôláìléérídá ÿákámôtótó cleaner n (substance)ohun èlò wíwç èérí cleaning n ìtôjú cleanliness (n)ìmô-tótó clear adj láìsí àbawönmô-tótómôjúdá-ÿákámôlëláìlábùkùmô garaketekete clear v hàn láìÿeyèméjìmú-dánmú-kúrògbá-môpalèmô clearing n ìpalëmôìmúkúròìkókúrò clergy n àlùfáà ìjô clerk n/f aköwé clerk n/m aköwé clever adj öjögbôngbígbônonímòyelórílôpôlô client n/f abëwë alágbàwíçlêjô client n/m abëwë alágbàwíçlêjô clientele n oníbàárà cliff n bèbè òkúta climate n afêfê ilëàkókòìgbà climax n òpinÿónÿó climb v gùngòkèpôn climber n/f çnití ngun òkè climber n/m çnití ngun òkè cling v somôwà môfà-môrömô clinic n ilé ìtôjú oríÿiríÿí ààrùn clinical (adj)níwà ìmôtótónípa ìtôjú ààrùn clock n agogo, aago clockwise (adv)bí agogo close (adv)súnmô close adj nítòsílêbàáödö close v padésétì closed adj títì pa closely (adv) tímôtímô môtí môtí pêkípêkí súnmôra típêtípê closet n yàrá-ìkökökôlôfín closure n ìparíòpin cloth n aÿôaÿô wíwunaÿô ìbora clothe v wö-laÿôfibònà-bò clothing (n)ohun wíwöaÿô wíwö cloud n ìkúùkùàwö-sánmàojú örunojú--sánmà cloudy (adj)gùdëgùdëÿú gùdë clove n ohun ögbìn olóòrùn dídùn clover n ìlàìpínëlà clown n aláwàdàoníyëyê club n (place)ilé ìpàdé çgbê club n (stick) kùmö, ögô clue n (idea)amönàiyé inúòye clump n ebè clumsy (adj)göpagunpagun clutch v díwôdìmújágbàbôsí clutter n aláìtò coach n (train)këkê olójú irin coach n/f (trainer)olùkô coach n/m (trainer)olùkô coal n çyìn ináèédú coalition n ìdàpöìÿökan coarse adj ÿàìkúnáÿaláìgbôngö ÿákíÿákí coast n etí òkunagbègbèìgbèríko coat n (animal)awô çranko coat n (clothing)aÿô ìlékèëwù àwölékè coating n ìlékèèpoìbora cobweb n okùn alántakùn cockpit n àyè ìjókòó atukö ôkö òfúrufú cockroach n aáyán cocoa n kòkó coconut n àgbôn cocoon n ewurukuekùkù | cod n irú çja kan code (n)àkôjô òfinènàkóòdù coerce v ÿàkósofagbára ÿefi agbára mú coffee n ohun mímu coffin n pósí coin n owó coincide v ÿe dédébá-muÿe-gêêÿe kòngê coincidence (n)ìÿedédéarobadeìÿegêêìÿekòngêìkôsèbá cold adj tutù cold n (illness)àmôdi cold n (temperature)òtútù collaborate v ÿe-pö collaboration n ìÿepöajùmöÿepö collapse v wó lulëbô sílë ÿe àìleradi asán collar n aÿô ìÿöÿô têré collarbone n egungun tó dé èjìká collateral n adáwìnohun ìdógóìlélë colleague n/f çgbêalábàáÿeçlêgbê colleague n/m çgbêalábàáÿeçlêgbê collect v kójôÿàjôgbájôdá-jô collection n ìkójôpöìÿàjô college n ilé-ìwé gíga collide v kôluradìgbòlù collision n ìkôluraìdìgbòlù colonel n ögágun àgbà colonize v tç ìlú dómú-lêrú colony (n)ìlú tí a të dó color n àwöìríìwöönà colorful (adj)aláwöôlônö colt n ômô çÿinômô kêtêkêtêagódóngbó column n (building)ìlàöwön comb n òyà ògbè ori àkùkô comb v yà combat n ìjàìdèlônà combat v jàdèlônàdojújàkô combination (n)çgbêìmöpöìkójôpöàjùmöàkópöàdàpö combine v dà-pörê-pö come v wásúnmôdödé comedian n/f aáwàdàaÿàwàdàoníyëyêapanilêërín comedian n/m aláwàdàaÿàwàdàoníyëyêapanilêërín comedy n àwàdàyëyê comet n ìràwö ìràwö ojú örunìràwö onírù comfort n ìtùnúìturaìrôraìpç comfortable (adj)nírôranítùnú comic n/f apanilêërín comic n/m apanilêërín, aláwàdà comical adj tí npanilêërín comma n àmì ìdádúró command n àÿçàkósoìjánu command v pàÿçÿàkósoko ni nijanu commander (n)olóríalákòósoaláÿç commandment (n)òfin commence v bërë pilë commend v yìnkíyêsí commendable adj ìyìn commendation (n)ìyêsíìyìn comment (v)làdìtúmösô àsôyé comment n ìlàdììtumöàsôyé commentary n ìwé ìtumöìwé ìlàdììwé àsôyé commerce n ìÿòwò, owó commission n ìfifúnniàÿçIÿêèrè commit v (crime)rú ofin commitment n ìlérí committee n àjô, ìgbìmõ, çgbë common adj wôpöbákannáàti gbogbo ènìà commotion n ìrúkèrúdò commune n ìjùmöpö communicate v sô-fún, fi-hàn, fi-fún, jùmö báÿepököwé communication (n)öröìfifúnìköwé communion n ìdàpöÿökan Onjê-alê Olúwa communism n nípa ìdàpöÿíÿökan communist n/f alájôgbé bùkátà communist n/m alájôgbé bùkátà community n ará ìlúçgbê commute v rin önà jínjìn lô sí ibi iÿê compact adj lëmôrafaramôradìlùÿinÿinwàpö companion n/f çlêgbêojúgbà çnìkejìögbà companion n/m çlêgbêojúgbà çnìkejìögbà companionship n ti çlêgbêàjôrìn company n (military) çgbë ômô ogun company n (business)çgbê company n (social)çgbêàjô comparable (adj)tí a lè fi wéra wôntí a lè fi wé compare v fiwéfiwéra comparison n àfiwéraìfiwéraìfiwé compartment n ìpínàyèàyè ìjókòó nínú ôköàyè fún çrù nínú ôkö compass (n)àyíkáòbìrìkìtì compassion n àánúìyônúìbákêdùn compatible adj yçtôsíbámuÿàìtàséwö pëlú compensate v san-fúnsanpadà fúnÿe àtúnÿe compensation n ìsanpàdàësanàtúnÿe compete v jàdú, dù, bá dù, jìjàdù, fàgagbága competence n títôyíyçòye competent adj tôlóye tóyç competition n ìjàdùìdíjeìje competitive adj níjàdùabánidù competitor n/f ajìjàdùadíjeabánidù competitor n/m ajìjàdùadíjeabánidù compile v tò sínú ìwèkójôÿàkójô ìwé complacency n ìtêlôrùnìdùnnú complacent (adj)nítëlôrùn complain v fi-súnÿàròyéráhùnrojô complaint n çjôësùnàrùnìráhùn complete adj (entire)kúnpé complete v (finish) ÿe-tánparí completely (adv)pátápátáyányánbìríjálëjálë completion n ìparí êkún, pipe, àÿepé, òpin, ìpêkun, ànítán, ìÿeparí complexion n àwö, àwö ojuìrísí compliance n ìjêwôgbígbàfífê complicate v díjúlôlù complication n ìdíjúìlôlù compliment n ìkíniìbuyìn comply v jêfêgbà fìmöÿö kantësí component n orí ëyàapákànkan nkan tí a fi ÿe odindin composure n ìfarabalëìkórajô comprehend v mö yé mòye comprehension (n) ìmöyeòye comprehensive adj ti ìkómôraláìbùkùçlêkùntí ó kó nkan púpö môra compress v fúnfún-pötë-pökìmôlë compromise v parí ìjàmú-rê compromise (n) ìlàjààdéhùn compulsive adj ìfagbáraÿení pákáõlekèaláraàìbalëìwà-ipátí nfi ìkánjú ÿe nkan láìrònútí nfi gírímônkáyì ÿe nkan compulsory adj dandanfagbáraÿepëlú-ipá computer n ërô olóye kömpútà comrade n/f çnikejìolùkùçlêgbê comrade n/m çnikejìolùkùçlêgbê conceal v fi-pamôfi-sin concede v gbàjêwôfi-fúngbà bí òtítôgbà láìjiyànfi sílëfi jíìnkí conceited adj tí íÿe gbígbôn lójú ara çni conceive v lóyúnròÿebífêrakù concentrate v fi-ojúsíkô arasírò-jinlëfi-ôkàn sí concentration n àrò jinlëìfôkànsíbìkan concept n èrò conception n (thought) èròìÿebí concern n ìÿeàníyànìfiyèsíohun tó kan ni concerning (prep)nípatiníti concert n iré orinìfìmöÿökan concession n ìjôlôwôìfifúngbígbà concise adj kúrúníbaÿókí conclude v ÿe paríÿetánpinnurò sipayàn jç conclusion n ìparíìÿetánìpinnuòpinìgúnlëàgbálôgbábö conclusive adj láìríwísíláìÿiyèméjìláìÿe-àníàníapayànjçláìlèdálóhùn concrete n pàtàkìàpòpö sèmêntìiyanrìn àti òkútaàrídìmú concussion n ìkôlù ìlúpö condemn v báwídá-lêbi condemnation n ìdálêbiëbiìbáwí condensation n dídìrírogúnkíki condense v dìkidílurogún condition n ipòìwàkání conditional adj àìdájú condolences n ìbákêdùnìbáÿedáròìtùnínú condone v faramôgbàláyèÿàìbáwí conduct n (behavior)ìwàìÿe conduct v (lead)fönàhànsìnÿe àkósoÿe conductor n/f amönàalákòósoakéròagbèròolùfönàhàn conductor n/m amönàalákòósoakéròagbèròolùfönàhàn confederation n ìmúlëìrêpöìdìmö pö confer v fi-fúnbá-söröjô sô conference n ìjùmösôìsöröàpéjôàpéròàjôsô confess v jêwô, gbà confession n ìjêwô confide v finú tánfôkàn tángbêkëlé confidence n ìgbêkëléìláiyàìfôkàntánìfôkànsô confident adj dídájúláìsí àníàní confidential adj ohun ìgbêkëlélíláìyà confine v há-möfi sêwöntìmôléÿe àkóso fi àlà sí confinement n ìbímôìhámôìtìmôlé confirm v tçnumôfçsë múlëmú lôkàn lejêwô confirmation n ìtçnumôìfçsmúlëìjêwôìmúlôkànleìfôwôlélórí confiscate v gbà gbà fún ìjôba lônà ìjçníyàbolé confiscation n ìbolégbígbà gbígbà fún ìjôba conflict n ìjàìkôlùraìwayá-ìjà conflicting adj ti ìjàohun tàbí iyè méjì tí nkôlu ara wôn confront v dojúkôkò-lójú confrontation (n)pèníjàìkòlójúìdojúkô confuse v dá-rúpòrúrùùdà-láàmúdabarúÿìmú confusing adj tí ó rú nilójú confusion n ìdàrúdàpö ìdàmú àìlójú rúdurùdu ìdàláàmú àÿìmú congestion n híháìkún détí congratulate v bá-yöyö-fúnyìnkí congratulations (n)yíyëfúnbíbáyöìyìnìkíni congregation (n) ìjô ènìàìpéjôàpéjôìjôàjô congress n àjôìpéjôàjô àwôn ìjòyèàjô ìgbìmöirú ìjôba kan connect v so-pöbá-tanbá-dàpöfi ara koratan mô connection (n)ìsolùpöìfarakoraìbátan conquer v ÿêgun, ÿëtë borí conquest n ìjàogunìÿêgunìÿëtë conscience n êrí ôkàn conscious adj mímö sínú consciousness (n)ìwà nípò àìsùn-àìjí consent n ìfohùnsôkàngíigbàìlohùnsíìjêwô consent v gbàjêwôfohùnsí consequence (n)àÿçìjásíìdí ìparíòpin iìgbëhìnàbájáde conservation n ìlòníwönba consider v rò ròwòdárògbàrògbéròkíyèsígbìmöràn considerable adj jê ní rírò considerably (adj)nírírò considerate adj nírònútí ngba ti çlòmíràn rò consideration n ìfiyèsíìròìyìnèròìmöràn considering (prep)bí a bá rò consist v níjêwà consistent adj dúrókidìluwà bákannáàdúró láìyçsëàìtàséra consolidate v sô di õkan consonant n ìsôdökanísôdilílekôñsónántì conspiracy n ìdìtëìdìmôìkökörìkíÿítëmbëlëkúnötë constable n/f ôlöpàá constable n/m ôlôpàá constant adj dídúróÿinÿintí kò yípadà ÿòótô constantly (adv)lemôlemôléralérafírífírínígbàgbogbo constipation n àìrígbêyàdídì inúàìyàgbê constitution n òfinëdá ara construct v kôÿe kànhun construction n kíkôÿíÿe kíkànìÿërôìtúmô ôrôëhun consul n aÿojú ìjôba kan ní ilë míràn consulate n oyè aÿojú ìjôba kan ní ilë míràn consult v béèrèfi öràn löwáàdí öröròjíròrò consultant n/f agbani nímörànapèròalámörànçnití nÿIÿê apèrò consultant n/m agbani nímörànapèròalámörànçnití nÿIÿê apèrò consultation n ìjùmösörö, ìbéèrè, ìförànlö, àpèwò apèrò ìbádámöràn consumption n àmódi àìyáàrùn ëdöfúru jëdöjëdö contact n (person) ìfarakanra contact v fi ra kanraÿe ìpàdé contagious adj ríràn contain v fi-pëlúgbà-sínúní nínú container n àpótíagolo contaminate v bà-jê contamination n ìbàjê contemplate v ÿe-àsàròronúwò contemplation n ìròàsàròwíwò contempt n ëgànìkêgànàìkàsíwíwò kìnúnìfojú tínrín ìrífín contemptible (adj)lêgànláìníláríÿàìní lárí content adj nítëêlôrùn contest v jàjiyànja ìjàdù context n ögangan ipò continent n orí ëyà àgbáyé continually (adv) títí títílô léraléra continuation n ìfàpêtítíàìdúróìbálôítësíwájú continue v të-síwájúdúró pêpêmúra síbá nÿó jingíriwà títí continuous adj àbálé-àbálé contour n àwòrán ilëilà ilë contraband n ohun ìlòdì sí òfinohun tí òfin kö contraception n önà ìdíwô oyún níníògùn ìdíwô oyún contraceptive n ogun ìdíwô oyún contract n ìpínhùnàdéhùnìpinnu contraction n (birth)ìrora ìbímô contradict v jì-lêsëjà-níyàntakòjá ní korogbó-lênu contradiction n ìjiyànìjílêsëìtakòìtakora contrary n ìlòdììyàtö-fún contrast n ìfiwéraìfìyàtö síìyàtö contribute v dá fi-fúnrànlôwôdá owó contribution n ìdáwóìrànlôwô control n (power)agbára ìjánu control v káwôkó níjàánuÿàkóso controversy n àròyé àsô ìjiyàn àríyànjiyàn gbólóhùn asö convalescence n bíbôlôwô àrùn, ìwòsàn lílágbára lêhìn ìwòsàn convene v pe àpèjô convenience n ìrôra ìrôrùnànfàní convenient adj yçrôrùnÿe-dédéwöÿànfànípèsè convention n àjô àpéjôàÿà conversation n örö sísôàsôgbà conversion n ìyípadàìyílôkànpadà convert v yí-padàyílôkàn-padà convey v mú-lôrùfi-fúnrán convict n/f çlêwönçnití a dálêbiçnití a dálêjô convict n/m çlêwönçnití a dálêbiçnití a dálêjô convict v ìdálêbiì dálêjôfi-sêwön conviction n (law)ìdálêbiìdálêjô convince v dá-ni lójúyí lôkàn padàfi òye yé convincing adj ohun ìdánilójúdídánilójú convulsion n ipágìrìipá-örërëàìperí cook n/f alásèase-onjç cook n/m alásèase-onjç cook v sè se ohun jíjç cool adj tútù fêri cool v mú tútùmú fêri cooperate v bá-ÿíÿe pöjùmöÿe cooperation n ìfowósowópöìbáÿepöàjùmöÿe cooperative adj ìbáÿepöàjùmöÿe coordinate v tò-pöÿe ètò coordination n títòpöÿíÿe ètòàmójútó copper n bàbàowó kôböàkàngbà copy n ëdà àwòkô ìwé-kíkô àtúnkô àpçrç àwòrán ìdàkôsílë copy v kô àwò-kôÿe àfarawédà kôsílë coral n iyùnìlëkë cord n okùn core n inú ohun kóhun cork n èdìdì ìgòìdênu corkscrew n ìÿígòìÿôtí corn n (eat)àgbàdoôkàyanganôkà bàbà corner n köröìkököìgunkôlôfínorígunkôrôgun coronation n ìdádéìfi ôba joyèìgba adéìgun orí ìtêìwúyè corporal n (military)olóyè ológun corporation n (company) àjô corpse n òkú ènìà correct adj títô correction n ìtôsônàìbáwíìtôniëtôàtúnÿe correspond v dáhùnÿe dédéköwé síbámubá dôgba correspondence n ìwé ìköwékíkô ìÿedédé ìbárê ìbámu ìbádôgba correspondent n/f akòwé ìwé ìròhìn correspondent n/m akòwé ìwé ìròhìn corresponding (adj)bíbáramudídôgbaÿíÿedédé corridor n ödëdë corrupt adj bíbàjêrírà corruption n ìwà ìbàjêàìmöíbàjêàbëtêlë cost n iyeiye owóìnáwóiye tí a ra nkanìnáwó çjô cost v nájê costly adj ÿeiyebíyeÿöwônníyelóríwônná ni lówótí ó ní owó lórí costume n aÿô wíwöëwùaÿô eré cottage n ilé kékeré cotton n òwúëfç òwú cough n ikô cough v wúkôhúkô council n àjô ìgbìmö counsel n ìmörànagbçjôròlôyà counsellor (n /f)olùdámörànabánipèròonímörànolùgbìmö counsellor (n /m)olùdámörànabánipèròonímörànolùgbìmö count v kà rò ÿírò counter n (window)fèrèsé counterfeit (v)tàn-jçÿe aíyédèrú counterfeit adj aíyédèrú counterfeit n ìtànjçaíyédèrú countless adj aìníyéaìmoye country n (land)ilë ilê ìbí çniìlú country n (nation)orílë èdè coup n ötëìdàlúrúìda ìjôba òÿèlú rú couple n (two) méjì couple n (people) ìsopö tôkô-taya courage n ìláiyàìlôkànìgbójúìgbóiyààìyà-níníìkìyà courageous adj akôniláìyànígboiyàgbóiyà course n ipa önàeré ìjeilë ibi ìsáré ìjeoríÿi onjç nì ìjoòkó lêëkan court n (law)ilé çjôàafingbangba ìÿiré courtesy n ìbuyìn-fúnìnínúrereöyàyà courthouse n ilé ìdájôilé çjô courtroom n ilé çjô courtyard n àgbàlá cousin n (m/b/o/d) ômôbìnrin ëgbôn ôkùnrin ìyá cousin n (f/o/b/d) ômôbìnrin ëgbôn okunrin baba cousin n (f/o/b/sn) ômôkùnrin ëgbôn ôkùnrin baba cousin n (f/s/o/d) ômôbìnrin ëgbôn obìnrin baba cousin n (f/s/o/sn) ômôkùnrin ëgbôn obìnrin baba cousin n (f/s/y/d) ômôbìnrin kékeré ëgbôn tàbí àbúrò obìnrin bàbá cousin n (f/s/y/sn) ômôkùnrin kékeré ëgbôn tàbí àbúrò obìnrin bàbá cousin n (f/y/b/d) ômôbìnrin kékeré àbúrò obìnrin bàbá cousin n (f/y/b/sn) ômôkùnrin kékeré àbúrò obìnrin bàbá cousin n (m/b/o/sn) ômôkùnrin ëgbôn ôkùnrin ìyá cousin n (m/b/y/d) ômôbìnrin àbúrò ôkùnrin ìyá cousin n (m/b/y/sn) ômôkùnrin àbúrò okùnrin ìyá cousin n (m/s/o/d)omobìnrin agba ëgbôn obìnrin ìyá cousin n (m/s/o/sn) ômôkùnrin agba ëgbôn tàbí àbúrò obìnrin ìyá cousin n (m/s/y/d) ômôbìnrin kékeré ëgbôn tàbí àbúrò obìnrin ìyá cousin n (m/s/y/sn) ômôkùnrin kékeré ëgbôn tàbí àbúrò obìnrin iya cover n ààbò, ìbora, ômôrí, ìdérí cover n bòdédábòbò cow n abo màluu coward n ojo coyote n irú çranko kançhànnà ajá crab n akàn crack n lílàsísán cradle n ìbùsùn ômôdé craftsman n oníÿönà crafty adj lôgbôn àrekérekè cramp n pajápajáìsúnrakììfúnpöìfàmôra crane n (bird)orúkô çyç kan bíi àkö crane n (machine) ërô àfigbêrùsókèërô ìgbêrùsôkö crash n ariwoÿíÿe crater n ihò nlá crave v àfêjùfì ìtara bëbëfìtara fêràn nkan crawl v rákòwôfà crazy adj fífôÿìwèrè cream n ôrá wàràìréjú wàràörá ìpara create v dáÿemú-jádedá sílëtinúdá creation n ëdáìÿeàtinúdá creative adj l'êbùn ìÿç ônàalátinúdá creature n ëdá credentials n àmì ëríìwé ohun ëríohun ërí credibility n ìyç nì gbìgbàgbôgbágbôgbígbàgbô credit n ìgbàgbôôláìwà rereàwìn cremate v ÿe sísun òkú cremation n sísun òkú crescent n àbö òÿùpá crew n çgbê àwôn atuköçgbê òÿìsêôlôwàöwà crib n ìbùjç çranìbúsùn ômôdé cricket n ìrë aláàntètèeré bôlù òyìnbó crime n ëÿërírú òfinìwàkíwàìwà búburú criminal n arúfinçlêÿëödaràn cripple n/f arô cripple n/m arô crisis n òpinkongbari critical adj àdájôlêgànlárìwísí criticism n ìÿe ìdájôwíwádììÿòfintótóàríwísíörö lámèyìítô criticize v ÿe ìwádìídí-yelégànÿe àkíyèsíÿòfintótó crocodile n önì jomijoke, çlêgungùn crooked adj (shape) daríkôkôdôrôgbígbunwíwôtëàiÿetàràkôrôkörô crop n (harvest)èso oko cross n àgbéléèbúìyà crossing n oríta crouch v tçríba fúnrö këkê fúnbërë crow n kanna-kánná crowd n öpö ènìàìkójôpöihágágáìbilù crowded adj ha gídagídahá gágá crown n adéfìlà ôbaowó fàdákà kan (ÿílè márùn-ún) cruel adj níkààìÿènìàìÿìkàláìníyônu cruise n ìjç fàájì nínú ôkö ojú omi cruise v wa-kö ojú omi kiri fún ìpolówó ökö tà cruiser n ôkö tí nkiri lójú önà tàbí lójú omi crumb n ërùnèwó crusade n ohun ìfìgboyà dáwôléogun àwôn onígbàgbô crust n (bread)èpa àkàrà òyìnbó crutch n öpá arô öpá akésë cry n (call) igbe ìpèníjà cry v (weep)sôkúnkígbe crystal n òkúta mímô gara cucumber n apala culprit n çlêÿëçni ìbáwíòdaran cult n awo cultivate v (crop)roro okoro ilë cultural adj nípa ti àÿà ìbílëìÿëÿeàbáláyé culture n àÿà ìbílëojú lílàríroko cup n agoìgò cupboard n pçpçibi àpamô èlò ónjçilé ìpamô ohun cure n ìwósànìmúláradáàwòtán cure v wòsànÿàwòtánmúláradá curiosity n àwáríìríìdíohun ìyanuohun àbàmìòfíntoto curious adj ÿöwônìyanilênuàbàmìalárà currency n owó nínáowó tákàdáìgbà ìsìsìyí current adj títàn kalëìsìsìyítìwòyítìgbàyí current n (water)ìÿàn odò currently adv nísisìyínígbàyílôwôlôwô curse n èpèègúnìfibúìgégún curse v ÿépèfi ÿépèfi-búfi-régéègún curtain n aÿô títaaso ìkéléìbojú ìtàgè curve n ohun tí a të cushion n tìmtìmìrôrí custody n ìhámôìÿôìdèìtìmôlé custom n àÿà ìÿeìÿëdálëìwà búburúìlò customary adj gêgê bí àÿàgêgê bí ìÿe customer n/f oníbàárà customer n/m oníbàárà customs n owó òdeowó bodè cut v gé kéÿáyún cut n ôgbê cycle n (series) öwô ìtëlêlêsesçàyíkáàyíkàn cylinder n agolo gígùn gbôrô cyst n éwo |